作词 : Alexander Abolore Adegbola Akande
作曲 : Alexander Abolore Adegbola Akande/Salami Olusegun Mosope/Aigbedion precious Aisosa
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
Beginning of Wisdom
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
Ah ah
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kó rọ̀ láti ọ̀run
Kó sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Láti òkè rere sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Gbé mi borí ọ̀tá sọ mí di’re
(Ẹ̀là rọ̀ wà ah Ẹ̀là)
Má wo búburú mi sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là mo bẹ̀ ẹ́
Ẹ̀là mo júbà
Ẹ̀là mo rọ̀ ẹ́ o
Ẹ̀là mo júbà
Ọmọ awó di’gun r’ọ̀run
(Ká má ṣe rí ìnira)
Mo ti digun r’ọ̀run
(Kí n má ṣe rí ìnira)
Mo jagun ọdún tó kọjá
Ríríṣe mi ò yí ipò padà
Awo ò mi wá yin Ifá
Ifá ń yín Elédùmarè
Tan tan tan tan tan
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kó rọ̀ láti ọ̀run
Kó sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Láti òkè rere sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Gbé mi borí ọ̀tá sọ mí di’re
(Ẹ̀là rọ̀ wà ah Ẹ̀là)
Má wo búburú mi sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Báwo ni ma ṣe ṣé ṣá?
Ọ̀nà wo ni mà á gbe gbà?
Báwo ni ma ṣe ṣé ṣá?
Ọ̀tá ń retí ẹlẹ́yà
Wọ́n ń polongo
Wọ́n ń polongo òkìkí tí a à tíì ní
Wọ́n ń polongo
Ẹbọ aláròká, là á tíì rú
Òkè wo la à tíì dé o
Ẹbọ wo la à tíì rú o
Ọ̀dájú lọ̀rẹ́ ikú but Ifá á gbè wá o
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là rọ̀ wá Ẹ̀là
(Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kó rọ̀ láti ọ̀run
Kó sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Láti òkè rere sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Gbé mi borí ọ̀tá sọ mí di’re
(Ẹ̀là rọ̀ wà ah Ẹ̀là)
Má wo búburú mi sọ mí di ire
(Ẹ̀là rọ̀ wá ah Ẹ̀là)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là kí ikú r’ọ̀run rerè
(Awó rerè)
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
(It's Bizzle on the mix)
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là
Ẹ̀là ah ah Ẹ̀là

热门推荐| 1 | |
|---|---|
| 2 | |
| 3 | |
| 4 | |
| 5 | |
| 6 | |
| 7 | |
| 8 | |
| 9 | |
| 10 |